IDAJỌ ỌLỌRUN
Heb 9:27 “Niwọn bi a si ti fi lelẹ fun gbogbo enia lati kú lẹ̃kanṣoṣo, ṣugbọn lẹhin eyi idajọ:” Lati igba iwaṣẹ ni Ọlọrun ti jẹ Oludajọ fun gbogbo iṣẹ ọwọ Rẹ. A gbọdọ mọ bawo, igbawo ati idi pataki
Home » Sermons-Yoruga
Heb 9:27 “Niwọn bi a si ti fi lelẹ fun gbogbo enia lati kú lẹ̃kanṣoṣo, ṣugbọn lẹhin eyi idajọ:” Lati igba iwaṣẹ ni Ọlọrun ti jẹ Oludajọ fun gbogbo iṣẹ ọwọ Rẹ. A gbọdọ mọ bawo, igbawo ati idi pataki
RUTU GẸGẸ BI AWOKỌṢE. (IWE RUTU) Rutu 1:16: “Rutu si wipe, Máṣe rọ̀ mi lati fi ọ silẹ, tabi lati pada kuro lẹhin rẹ: nitori ibiti iwọ ba lọ, li emi o lọ; ibiti iwọ ba si wọ̀, li emi
Ẹyin Ayanfẹ Ilẹ Miṣẹni ati ẹyin ti a k’ọju si ṣe l’oore, ti a si yan, ti o tun ni anfani, lati jẹ ẹlẹri si, igba ati fifi Ọba titun Rẹ si ori oye, gẹgẹbi aṣooju BABA ni aarin awọn
Oore-ọfẹ! Ohun Adun ni l’eti wa; Gbo’un-gbo’un rẹ y’o gba ọrun kan, Aiye y’o gbọ pẹlu. Oore-ọfẹ ṣa N’igbẹkẹle mi; Jesu ku fun araiye, O ku fun mi pẹlu. Awọn kristiani maa nlo ọrọ yi – (oore-ọfe) laibikita, nitori nwọn
1. Ẹkọ Bibeli fun ọrọ iṣiti oni ni a mu lati Ihinrere Luku 8:1-3, eyi ti o ka wipe: “O si ṣe lẹhinna, ti o nlà gbogbo ilu ati iletò lọ, o nwasu, o nrò ìhin ayọ̀ ijọba Ọlọrun: awọn
Ninu idije idibo fun ipo Arẹ orilẹ edẹ Amẹrika, eyiti o waiye ni ọdun diẹ sẹhin; ni a ti ri Akọni kan, ninu idije du ipo Arẹ ni orilẹ ede naa, lara awọn oludije fun ipo nla agbanla aiye yi.
“ Jesu bi wọn lere wipe ṣugbọn tali ẹyin fi mi pe?” (Matthew 16:15) Ireti Ọlọrun si awa ẹda ọwọ Rẹ ni wipe ki a le ṣe ohun gbogbo gẹgẹbi ifẹ ati aṣẹ Rẹ, ani lati mọ otitọ Rẹ, otitọ